![]() |
|||||||
Contents | Display Settings | Font Settings | About | |||||||
Part 5: On consistency; honesty, openness, plain speaking, reliabilityOdot
Ọbẹ̀-ẹ́ dùn, ọbẹ̀ ò dùn, iyán tán nígbá.
Ọ̀kánkán là ńṣe ìbí; ìkọ̀kọ̀ là ńṣe ìmùlẹ̀; bí a tọ́jú ìmùlẹ̀ tán, ká tọ́jú ìbí pẹ̀lú; bí a bá kú ará ẹni ní ńsinni.
Ọ̀nà irọ́ kì í pẹ́ẹ́ pin.
Ọ̀mọ̀rán bèèrè ọ̀ràn wò; Àjàpá ní, “Ẹni tí wọ́n pa lánàá, kàà kú tán?”
“Ọ̀ràn yí ò dùn mí”: ẹ̀ẹ̀kanṣoṣo là ńwí i.
Ọ̀rọ̀ ìkọ̀kọ̀, ní gba-n-gba ní ḿbọ̀.
Ọ̀rọ̀ ò pariwo.
Ọ̀tá ẹni kì í pòdù ọ̀yà.
|
|||||||
![]() |