![]() |
|||||||
Contents | Display Settings | Font Settings | About | |||||||
Part 5: On consistency; honesty, openness, plain speaking, reliabilityP
Pàkìtí ṣe bí òkú wọ̀lú; labalábá ṣe bí ẹyẹ jáko.
Pátá-pátá; là ńfọ́jú, kùm̀bọ̀-kumbọ là ńdẹ́tẹ̀; ojú à-fọ́-ì-fọ́-tán ìjà ní ńdá sílẹ̀.
Pátá-pátá leégún ńfaṣọ borí;.
Pẹ̀hìndà kí o ríṣe èké, fara pamọ́ kí o rí bí aṣení ti ńsọ.
Pípọn niyì idẹ; ẹ̀jẹ́ niyì oògun.
Pọ̀ǹgbà-pọngba là ḿbá odi.
Purọ kóo níyì; bí a bá jáni tán, ẹ̀tẹ́ ní ńdà.
|
|||||||
![]() |