![]() |
|||||||
Contents | Display Settings | Font Settings | About | |||||||
Part 4: On perseverance, industry, resilience, self-confidence, self-reliance, resourcefulness, daring, fortitude, and invulnerabilityD
Dàńdógó kì í ṣe ẹ̀wù ọmọdé.
Dídán là ńdán ọ̀ràn wò; bí olówó ẹní kú, à lọ ṣúpó.
Dídán lẹyẹlé ńdán kú.
Díẹ̀-díẹ̀ leku ńjawọ.
Díẹ̀-díẹ̀ lẹyẹ ńmu ọsàn.
Díẹ̀-díẹ̀ ní ńtánṣẹ́.
Dùndún fọ̀ràn gbogbo ṣàpamọ́ra.
|
|||||||
![]() |