Contents | Display Settings | Font Settings | About | |||||||
Part 3: On cageyness, caution, moderation, patience, and prudenceG
Ganganran ò ṣéé kì mọ́lẹ̀; a-gúnni-lọ́wọ́-bíi-ṣoṣoro.
Gìdì-gìdì ò mọ́là; ká ṣiṣẹ́ bí ẹrú ò da nǹkan.
Gùdùgudu ò túra sílẹ̀ lẹ́ẹ̀kan.
Gùdùgudu-ú kan légbò kán-ín-kán-ín.
|
|||||||