![]() |
|||||||
Contents | Display Settings | Font Settings | About | |||||||
Part 3: On cageyness, caution, moderation, patience, and prudenceF
Fáàárí àṣejù, oko olówó ní ḿmú ọmọ lọ.
Fẹ̀hìntì kí o rí ìṣe èké; farapamọ́ kí; o gbọ́ bí aṣeni-í ti ńsọ.
Fi ẹ̀jẹ̀ sínú, tu itọ́ funfun jáde.
Fi ohun wé ohun, fi ọ̀ràn wé ọ̀ràn;fi ọ̀ràn jì ká yìn ọ́.
Fi ọ̀ràn sínú pète ẹ̀rín;fi ebi sínú sunkún ayo.
Fò síhìnín fò sọ́hùnún làkèré fi ńṣẹ́ nítan.
|
|||||||
![]() |