Contents | Display Settings | Font Settings | About

Part 3: On cageyness, caution, moderation, patience, and prudence

D

Dàda ò leè jà, ṣùgbọ́n ó lábùúrò tó gbójú.

Dágun-dágun Kaletu tí ńdá ìbejì lápá.

Dá-mìíràn-kún-mìíràn tí ńpa àpatà ẹyẹlé.

Dàńdógó kọjá ẹ̀wù àbínúdá; bí a bá ko ẹni tó juni lọ, a yàgò fún un.

Dá-ǹkan-dá-ǹkan, tí kì í dáṣọ̀, tí kì í dẹ́wù.

.
PreviousContentsNext