Contents | Display Settings | Font Settings | About | |||||||
Part 3: On cageyness, caution, moderation, patience, and prudenceL
Labalábá kì í bá wọn nájà ẹlẹ́gùnún; aṣọ-ọ ẹ̀ á fàya.
Labalábá tó dìgbò lẹ̀gún, aṣọ ẹ̀ á fàya.
Làákàyè baba ìwà; bí o ní sùúrù, ohun gbogbo lo ní.
Làálàá tó ròkè, ilẹ̀ ní ḿbọ̀.
Lù mí pẹ́, lù mí pẹ́ làpọ́n fi ńlu ọmọ-ọ ẹ̀ pa.
|
|||||||