Contents | Display Settings | Font Settings | About

Part 3: On cageyness, caution, moderation, patience, and prudence

J

Já ewé ọ̀pọ̀tọ́ kí o ríjà eèrùn; jáwé bọ ẹnu kóo ríjà odi.

Jayé-jayé fi ẹ̀lẹ̀ jayé; báyé bá já kò ní àmúso.

Jẹ ẹ́ kí o yó oògùn ni kò sunwọ̀n.

Jẹ́ kí ọmọ ó ti ọwọ́ ìyá-a ẹ̀ kú wá.

.
PreviousContentsNext