Contents | Display Settings | Font Settings | About | |||||||
Part 2: On perspicaciousness (good judgment, perceptiveness), reasonableness, sagacity, savoir-faire, wisdom, and worldly wisdomD
Dà-á-sílẹ̀-ká-tun-pín, ogún ijọ́un, a ò pín in re.
Dídì ní ḿmú abẹ mú.
Díẹ̀-díẹ̀ nimú ẹlẹ́dẹ̀ẹ́ fi ńwọgbà.
DÍfá-dÍfá ò fIfá ṣeré.
Dùgbẹ̀-dùgbẹ̀ kì í fi ẹyin rẹ̀ sílẹ̀.
Dúró o kíkà; bí o ò dúró kíkà, ìkà a ba tìrẹ jẹ́.
|
|||||||