Contents | Display Settings | Font Settings | About | |||||||
Part 1: On humility, self-control, self-knowledge, self-respect, and self-restraintSdot
Ṣágo ḿbúgò, ó ló ṣẹnu gbáṣọ́rọ́.
Ṣàgbà-ṣàgbà ò níí sé àgbà títí láí.
Ṣàkì ńṣe bí ọ̀rá, egungun ńṣe bí ẹran.
Ṣáláporẹ́ ò mọ ẹgbẹ́ ẹ̀ nínú omi.
Ṣe bóo ti mọ, ẹlẹ́wàa Ṣàpọ́n.
|
|||||||