Contents | Display Settings | Font Settings | About | |||||||
Part 1: On humility, self-control, self-knowledge, self-respect, and self-restraintT
“Ta ní ḿbẹ níbẹ̀?” làgbẹ́ fi ńsán ìbàǹtẹ́ wọ̀lú.
Ta ní mọ Òkolo lÓyọ̀ọ́?
Ta ní ńjájá ní mọ́ṣáláṣí?
Ta ní ńjẹun tájá ńjùrù?
Tẹ̀tẹ̀ kì í tẹ́.
Tòlótòló mọ ẹni tó ńyìnbọn ìdí sí.
|
|||||||