Contents | Display Settings | Font Settings | About

Part 1: On humility, self-control, self-knowledge, self-respect, and self-restraint

S

San là ńrìn; ajé ní ḿmúni pá kọ̀rọ̀.

Sesere ńdá gọ́ọ́bú; oníkamẹ́sàn-án ńgbé ṣíbí.

Sún mọ ọ̀hún, sún mọ́ ìhín! Bí a bá kan ògiri ilé-e baba ẹni, ṣe là ńdúró gbọin-gbọin.

.
PreviousContentsNext