Contents | Display Settings | Font Settings | About

Part 6: On consideration, kindness, and thoughtfulness

T

Tewé tegbò ní ńṣàánú àfòmọ́.

Tigi tọ̀pẹ̀ ní ńṣàánú àfòmọ́.

Tigi tọ̀pẹ̀ ní ńsàánú ìyèré lóko.

Tìkà toore, ọ̀kan kì í gbé.

Tútù ní ńtẹnu ẹja wá.

.
PreviousContentsNext