![]() |
|||||||
Contents | Display Settings | Font Settings | About | |||||||
Part 6: On consideration, kindness, and thoughtfulnessSdot
Ṣe sílẹ̀: ẹrù-u ẹ̀ kì í pẹ́ níbodè.
Ṣẹ̀gàn-ṣẹ̀gàn ò láṣọ méjì; pé-ń-pé laṣọ abúni ḿmọ.
Ṣìkà-ṣìkà-á fi díẹ̀ ṣe ara ẹ̀.
Ṣìkà-ṣìkà-á gbàgbé àjọbí, adánilóró gbàgbé ọ̀la.
Ṣìkà-ṣìkà ò jẹ́ pe ara ẹ̀ níkà.
|
|||||||
![]() |