![]() |
|||||||
Contents | Display Settings | Font Settings | About | |||||||
Part 6: On consideration, kindness, and thoughtfulnessOdot
Ọ̀gá Ìwátà, eṣú ò mọ olóòótọ́; eṣú dé, eṣú jẹ oko olóore.
Ọ̀mùtí kì í ṣàpà; owó ẹ̀ ló ńná.
Ọ̀ràn-an-yàn ò sí nínúu iyánrán.
Ọtí gbélé ahun ó kan.
Ọ̀tọ̀ niṣẹ́ olókùnrùn.
Ọwọ́ híhá àhájù ní ńdínà ire mọ́ni.
|
|||||||
![]() |