Contents | Display Settings | Font Settings | About

Part 5: On consistency; honesty, openness, plain speaking, reliability

T

Ta là bá rí báwí bí ẹní fọmọ fọ́kọ lóru, tí ò jẹ́ kílẹ̀ mọ́?

Ta la domi sí lára? Ta lòrìṣà ńgùn?

Ta leṣinṣin ìbá gbè bí kò ṣe elégbò?

Ta ló dè ọ́ tí ò ńkakọ?

Ta ní ńṣoògùn lódò tí lábẹ-lábẹ ò gbọ́?

.
PreviousContentsNext