Contents | Display Settings | Font Settings | About

Part 5: On consistency; honesty, openness, plain speaking, reliability

Sdot

Ṣìgìdì ò lẹ́nu fọhùn; irọ́ ńpurọ́ fúnrọ́.

Ṣìgìdì tí ò sọ̀rọ̀, a ò mẹni tí ńgbè.

.
PreviousContentsNext