Nì palaba, ní wonko, ẹ̀rẹ̀kẹ́ á ṣèkan.
Nígbàtí ọwọ́ ò tẹ ìjàdù là ńní kò sí ohun tí à ńjẹ tí kì í tán.