![]() |
|||||||
Contents | Display Settings | Font Settings | About | |||||||
Part 4: On perseverance, industry, resilience, self-confidence, self-reliance, resourcefulness, daring, fortitude, and invulnerabilitySdot
Ṣàngó ò lè pa igi ńlá.
Ṣe kóo ní; àbá ò di tẹni; èèyàn ò ṣoògùn ọrọ̀.
Ṣiṣe-é rorò, jíjẹ ọ̀fẹ́.
Ṣòkòtò gbọọrọ ò dọlà; abíni lÓÉkòó ò dowó.
Ṣòkòtò tí ńṣiṣẹ́ àrán, oko ní ńgbé.
|
|||||||
![]() |