![]() |
|||||||
Contents | Display Settings | Font Settings | About | |||||||
Part 4: On perseverance, industry, resilience, self-confidence, self-reliance, resourcefulness, daring, fortitude, and invulnerabilityP
Pa á ní ńjẹ́ ọgbẹ́, tiiri níńjẹ ọfà; bí a bá ta á ṣe là ńwá a; bí a ò bá wá a a dẹran ìdin.
Pà-pà lójú lẹ́ẹ̀kínní, pà-pà lójú lẹ́ẹ̀kejì; bójú náà ò bá fọ́, bàì-bàì ní ńdà.
Páńdọ̀rọ̀-ọ́ já, ará rọ ìyá ẹ̀.
|
|||||||
![]() |