Contents | Display Settings | Font Settings | About | |||||||
Part 3: On cageyness, caution, moderation, patience, and prudenceT
“Ta á sí i” kì í báni wá ọfà.
Ta ní rán Abẹ́lù wọ ọkọ̀, tó ní ọkọ̀ọ́ ri òun?
“Tàná là ńjà lé lórí”, ló pa Baálẹ̀ẹ Kòmọ̀kan.
Tantabùlù, aṣòróówọ̀ bí ẹ̀wù àṣejù.
Tìjà tìjà ní ńṣe ará Ọ̀pọ́ndá.
Tọ̀sán tọ̀sán ní ńpọ́n ìtalẹ̀ lójú; bílẹ̀-ẹ́ bá ṣú yó di olóńjẹ.
|
|||||||