Contents | Display Settings | Font Settings | About | |||||||
Part 3: On cageyness, caution, moderation, patience, and prudenceSdot
Ṣàǹgbákó ró, a ní kò róo re, Ṣàǹgbàkù-ú gbè é lẹ́sẹ̀.
Ṣe-ká-rí-mi, alájá tó so ẹ̀gi mọ́rùn.
“Ṣé kí nfìdí hẹ?” làfòmọ́ fi ńdi onílé.
Ṣe-ǹ-ṣe dìwọ̀fà, bó ṣe é yó dẹrú-u wọn.
Ṣe-ǹ-ṣe ewúrẹ́ làgùntàn ńfiyè sí.
|
|||||||