Contents | Display Settings | Font Settings | About | |||||||
Part 2: On perspicaciousness (good judgment, perceptiveness), reasonableness, sagacity, savoir-faire, wisdom, and worldly wisdomM
“Máa jẹ́ ǹṣó” lọ̀yà fi ńju ẹmọ́ lọ.
“Màá kó ẹrú, màá kó ẹrù” là ḿbá lọ sógun; ọ̀nà lẹnìkẹta ḿbáni.
Màjèṣín dóbò àkọ́kọ́, ó sáré yọ okó síta, ó ní Olúwa-á ṣeun.
Mójú-kúrò nilé ayé gbà; gbogbo ọ̀rọ̀ kọ́ ló ṣéé bínú sí.
|
|||||||