![]() |
|||||||
Contents | Display Settings | Font Settings | About | |||||||
Part 6: On consideration, kindness, and thoughtfulnessM
“Má bàá mi jẹ ìdùn,” ẹran ní ńlé lọ.
“Má fẹ̀ẹ́ ọwọ́-ọ̀ mi kù” tí ńyan gúgúrú fún eégún; eégún náàá ní “Má fẹ̀ẹ́ ọwọ́-ọ̀ mi kù”; ó fún un ní ọmọláńgidi.
M̀bá-lówó-m̀bá-se-ọ̀lẹ̀lẹ̀-fún-Agọ́n: ìjímèrè kì í jẹ oko ẹ̀ kó sọ̀.
“Mú wá, mú wá” lapá ẹyẹlé ńké.
|
|||||||
![]() |