Contents | Display Settings | Font Settings | About

Part 6: On consideration, kindness, and thoughtfulness

K

Kí á ṣá a ṣá a, kí á gbọ̀n ọ́n gbọ̀n ọ́n; ká fi oko eéran sílẹ̀ ló dá eéran lára.

“Kiní yìí ò pọ̀; ng ò lè fún ọ níbẹ̀”: olúwarẹ̀ ahun ni.

“Kiní yìí tí o fún mi ò pọ̀”: ahun ní ńjẹ́ bẹ́ẹ̀.

Kò mú ti ọwọ́ ẹ̀ wá ò gba tọwọ́ ẹni.

Kò sí kò sí; bẹ́ẹ̀ni ọmọ wọn ńyó.

Kò tó ǹkan ní ńsọni dahun.

.
PreviousContentsNext