Contents | Display Settings | Font Settings | About

Part 5: On consistency; honesty, openness, plain speaking, reliability

Gb

Gba-n-gba là ńṣe gbàǹgbà; bẹ́ṣín bá kú, ìta gbangba là ńsin í sí.

Gba-n-gba làṣá ńta.

Gba-n-gba lÒgèdèm̀gbé ńṣawo.

Gbogbo wa la fòkété san ọgọ́fà; ìgbà tí òkété ó fi di ogóje, ojú-u gbogbo wa ni yó ṣe.

.
PreviousContentsNext