Yíyọ́ ẹkùn, tojo kọ́; ohun tí yó jẹ ní ńwá.
Yọkọlú-yọkọlú, kò ha tán bí? Ìyàwó gbọ́kọ ṣánlẹ̀, ọkọ-ọ́ yọké.