Contents | Display Settings | Font Settings | About | |||||||
Part 3: On cageyness, caution, moderation, patience, and prudenceW
Wàrà ò sí lónìí, wàrà-á wà lọ́la.
Wẹ́rẹ́ wẹ́rẹ́ nikán ńjẹlé.
Wíwò-ó tó ìran.
“Wó ilé ẹ kí mbá ọ kọ”: ẹrù ikán kan ní ńpa fúnni.
Wọ̀bìà-á yó tán, ó pe ẹgbẹ́ ẹ̀ wá.
Wọ́n ní,; “Ìbàrìbá, ọmọ ẹ-ẹ́ jalè.” Ó ní “A gbọ́ tolè tó jà; èwo lokùn ọrùn-un ẹ̀'?”
Wọ́n purọ́ fún ọ, o ò gbà; o lè dé ìdí òótọ́?
Wọ́n torí ajá ńlóṣòó lọ fowó rọ̀bọ.
|
|||||||