![]() |
|||||||
Contents | Display Settings | Font Settings | About | |||||||
Part 3: On cageyness, caution, moderation, patience, and prudenceJ
Já ewé ọ̀pọ̀tọ́ kí o ríjà eèrùn; jáwé bọ ẹnu kóo ríjà odi.
Jayé-jayé fi ẹ̀lẹ̀ jayé; báyé bá já kò ní àmúso.
Jẹ ẹ́ kí o yó oògùn ni kò sunwọ̀n.
Jẹ́ kí ọmọ ó ti ọwọ́ ìyá-a ẹ̀ kú wá. 51. Fig leaves are usually infested with soldier-ants, and the deaf are supposed to be insulted by anyone who places a leaf in his/her mouth. [Back to text]
|
|||||||
![]() |