Contents | Display Settings | Font Settings | About

Part 2: On perspicaciousness (good judgment, perceptiveness), reasonableness, sagacity, savoir-faire, wisdom, and worldly wisdom

Gb

“Gba ọmọ fún mi kí nrèdí”; bí ìdí ò bá ṣe-é re ká gbọ́mọ fọ́lọ́mọ.

Gbogbo ẹranko ìgbẹ́ pé, wọn ní àwọn ó fi ìkokò ṣe aṣípa; nígbà tó gbọ́ inú ẹ̀-ẹ́ dùn; ṣùgbọ́n nígbà tó ṣe ó bú sẹ́kún; wọ́n ní kí ló dé? Ó ní bóyá wọ́n lè tún ọ̀ràn náà rò kí wọ́n ní kì í ṣe bẹ́ẹ̀ mọ́.

.
PreviousContentsNext