Contents | Display Settings | Font Settings | About

Part 1: On humility, self-control, self-knowledge, self-respect, and self-restraint

Y

“Yan àkàrà fún mi wá ká jìjọ jẹ ẹ́”: àìtó èèyàn-án rán níṣẹ́ ní ńjẹ́ bẹ́ẹ̀.
“Go buy bean fritters for me so we can eat them together”: that spells uncertainly about one's right to send the person concerned on an errand.
(People in authority should not be tentative in asserting their authority.)

Yíyẹ́ là ńyẹ́ Òkóró sí tí à ńpè é nígi obì; obì tí ì bá so lórí ẹ̀ ní ńya abidún.
It is only a mark of respect when one calls Òkóró a kolanut tree; any kolanut that might grow on his head would turn out to be slimy.
(People who enjoy the respect of others should not make the mistake of overestimating their importance.)

.
Contents