Contents | Display Settings | Font Settings | About | |||||||
Part 1: On humility, self-control, self-knowledge, self-respect, and self-restraintP
Pamí-nkú obìnrín ṣorí bẹmbẹ sọ́kọ.
Pátápátá alágbẹ̀dẹ ò ju ilé àrọ lọ.
Pẹ̀lẹ́ larẹwà ńrìn; jẹ́jẹ́ lọmọ ọlọ́jà ńyan.
[88]
Pẹ̀lẹ́-pẹ̀lẹ́ nijó àgbà; ara gbogbo ló di àkísà tán.
Pẹ̀tẹ̀pẹ́tẹ̀ Ìjèṣà, ó ta sẹ́ni lára kò wọ́n. 89. Most probably this is a riddle doing double duty as a proverb. The riddle, Pẹ̀tẹ̀pẹ́tẹ̀ ọ̀nà Ìjàyè, atasíniláramáwọ̀ọ́n (The mud along Ìjàyè way that splashes on one and cannot be removed), has as its solution, facial scarification. [Back to text]
|
|||||||